1
ORIN DAFIDI 23:4
Yoruba Bible
Àní, bí mo tilẹ̀ ń rìn ninu òkùnkùn létí bèbè ikú, n kò ní bẹ̀rù ibi kankan; nítorí tí o wà pẹlu mi; ọ̀gọ rẹ ati ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 23:4
2
ORIN DAFIDI 23:1
OLUWA ni Olùṣọ́-aguntan mi, n kò ní ṣe àìní ohunkohun.
Explore ORIN DAFIDI 23:1
3
ORIN DAFIDI 23:6
Dájúdájú, ire ati àánú yóo máa tẹ̀lé mi kiri, ní gbogbo ọjọ́ ayé mi; èmi óo sì máa gbé inú ilé OLUWA laelae.
Explore ORIN DAFIDI 23:6
4
ORIN DAFIDI 23:2-3
Ó mú mi dùbúlẹ̀ ninu pápá koríko tútù, ó mú mi lọ sí ibi tí omi ti dákẹ́ rọ́rọ́; ó sọ agbára mi dọ̀tun. Ó tọ́ mi sí ọ̀nà òdodo nítorí orúkọ rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 23:2-3
Home
Bible
Plans
Videos