1
ORIN DAFIDI 24:1
Yoruba Bible
OLUWA ló ni ilẹ̀ ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀, òun ló ni ayé, ati gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀
Compare
Explore ORIN DAFIDI 24:1
2
ORIN DAFIDI 24:10
Ta ni Ọba ògo yìí? OLUWA àwọn ọmọ ogun, òun ni Ọba ògo náà.
Explore ORIN DAFIDI 24:10
3
ORIN DAFIDI 24:3-4
Ta ló lè gun orí òkè OLUWA lọ? Ta ló sì lè dúró ninu ibi mímọ́ rẹ̀? Ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ mọ́, tí inú rẹ̀ sì funfun, tí kò gbẹ́kẹ̀lé oriṣa lásánlàsàn, tí kò sì búra èké.
Explore ORIN DAFIDI 24:3-4
4
ORIN DAFIDI 24:8
Ta ni Ọba ògo yìí? OLUWA tí ó ní ipá tí ó sì lágbára, OLUWA tí ó lágbára lógun.
Explore ORIN DAFIDI 24:8
Home
Bible
Plans
Videos