1
ORIN DAFIDI 25:5
Yoruba Bible
Tọ́ mi sí ọ̀nà òtítọ́ rẹ, sì máa kọ́ mi, nítorí ìwọ ni Ọlọrun olùgbàlà mi; ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé ní ọjọ́ gbogbo.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 25:5
2
ORIN DAFIDI 25:4
Fi ọ̀nà rẹ hàn mí, OLUWA, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 25:4
3
ORIN DAFIDI 25:14
Àwọn tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni OLUWA ń mú ní ọ̀rẹ́, a sì máa fi majẹmu rẹ̀ hàn wọ́n.
Explore ORIN DAFIDI 25:14
4
ORIN DAFIDI 25:7
Má ranti ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ti ṣẹ̀ ní ìgbà èwe mi, tabi ibi tí mo ti kọjá ààyè mi; ranti mi, OLUWA, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ati nítorí oore rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 25:7
5
ORIN DAFIDI 25:3
OLUWA, má jẹ́ kí ojú ó ti ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé ọ; àwọn ọ̀dàlẹ̀ eniyan ni kí ojú ó tì.
Explore ORIN DAFIDI 25:3
Home
Bible
Plans
Videos