1
ORIN DAFIDI 26:2-3
Yoruba Bible
Yẹ̀ mí wò, OLUWA, dán mi wò; yẹ inú mi wò, sì ṣe akiyesi ọkàn mi. Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni mo tẹjúmọ́, mo sì ń fi òtítọ́ bá ọ rìn.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 26:2-3
2
ORIN DAFIDI 26:1
Dá mi láre, OLUWA, nítorí ninu ìwà pípé ni mò ń rìn, mo sì gbẹ́kẹ̀lé OLUWA láìṣiyèméjì.
Explore ORIN DAFIDI 26:1
Home
Bible
Plans
Videos