1
ORIN DAFIDI 27:14
Yoruba Bible
Dúró de OLUWA, ṣe bí akin, kí o sì mú ọkàn gírí, àní, dúró de OLUWA.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 27:14
2
ORIN DAFIDI 27:4
Ohun kan ni mo ti tọrọ lọ́dọ̀ OLUWA, òun ni n óo sì máa lépa: Kí n lè máa gbé inú ilé OLUWA ní gbogbo ọjọ́ ayé mi, kí n lè máa wo ẹwà OLUWA, kí n sì máa fi tọkàntọkàn sìn ín ninu tẹmpili rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 27:4
3
ORIN DAFIDI 27:1
OLUWA ni ìmọ́lẹ̀ ati ìgbàlà mi; ta ni n óo bẹ̀rù? OLUWA ni ààbò ẹ̀mí mi, ẹ̀rù ta ni yóo bà mí?
Explore ORIN DAFIDI 27:1
4
ORIN DAFIDI 27:13
Mo gbàgbọ́ pé n óo rí oore OLUWA gbà ní ilẹ̀ alààyè.
Explore ORIN DAFIDI 27:13
5
ORIN DAFIDI 27:5
Nítorí pé, nígbà tí ìpọ́njú bá dé, yóo fi mí pamọ́ sinu àgọ́ rẹ̀, lábẹ́ ààbò, ninu àgọ́ rẹ̀, ni yóo fi mí pamọ́ sí; yóo sì gbé mi sókè ka orí àpáta.
Explore ORIN DAFIDI 27:5
Home
Bible
Plans
Videos