1
ORIN DAFIDI 28:7
Yoruba Bible
OLUWA ni agbára ati asà mi, òun ni mo gbẹ́kẹ̀lé; ó ràn mí lọ́wọ́, ọkàn mi sì kún fún ayọ̀; mo sì fi orin ìyìn dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 28:7
2
ORIN DAFIDI 28:8
OLUWA ni agbára àwọn eniyan rẹ̀; òun ni ààbò ìgbàlà fún ẹni àmì òróró rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 28:8
3
ORIN DAFIDI 28:6
Ẹni ìyìn ni OLUWA! Nítorí pé ó ti gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.
Explore ORIN DAFIDI 28:6
4
ORIN DAFIDI 28:9
Gba àwọn eniyan rẹ là, OLUWA, kí o sì bukun ilẹ̀ ìní rẹ. Jẹ́ olùṣọ́-aguntan wọn, kí o sì máa tọ́jú wọn títí lae.
Explore ORIN DAFIDI 28:9
Home
Bible
Plans
Videos