1
ORIN DAFIDI 30:5
Yoruba Bible
Nítorí pé fún ìgbà díẹ̀ ni ibinu rẹ̀, ṣugbọn títí ayé ni ojurere rẹ̀; eniyan lè máa sọkún títí di alẹ́, ṣugbọn ayọ̀ ń bọ̀ fún un lówùúrọ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 30:5
2
ORIN DAFIDI 30:11-12
O ti bá mi sọ ọ̀fọ̀ mi di ijó, o ti bọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ kúrò lára mi, o sì ti dì mí ní àmùrè ayọ̀, kí ọkàn mi lè máa yìn ọ́ láìdákẹ́. OLUWA Ọlọrun mi, n óo máa fi ọpẹ́ fún ọ títí lae.
Explore ORIN DAFIDI 30:11-12
3
ORIN DAFIDI 30:2
OLUWA, Ọlọrun mi, mo ké pè ọ́, o sì wò mí sàn.
Explore ORIN DAFIDI 30:2
4
ORIN DAFIDI 30:4
Ẹ kọ orin ìyìn sí OLUWA, ẹ̀yin olùfọkànsìn rẹ̀, kí ẹ sì fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 30:4
5
ORIN DAFIDI 30:1
N óo yìn ọ́, OLUWA, nítorí pé o ti yọ mí jáde; o kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi ó yọ̀ mí.
Explore ORIN DAFIDI 30:1
Home
Bible
Plans
Videos