1
ORIN DAFIDI 31:24
Yoruba Bible
Ẹ múra gírí, kí ẹ sì mọ́kàn le, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ gbẹ́kẹ̀lé OLUWA.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 31:24
2
ORIN DAFIDI 31:15
Ìgbà mi ń bẹ ní ọwọ́ rẹ; gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi, ati lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi.
Explore ORIN DAFIDI 31:15
3
ORIN DAFIDI 31:19
Háà! Ohun rere mà pọ̀ lọ́wọ́ rẹ o tí o ti sọ lọ́jọ̀ fún àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ, tí o sì ti pèsè ní ìṣojú àwọn ọmọ eniyan, fún àwọn tí ó sá di ọ́.
Explore ORIN DAFIDI 31:19
4
ORIN DAFIDI 31:14
Ṣugbọn, mo gbẹ́kẹ̀lé ọ, OLUWA, Mo ní, “Ìwọ ni Ọlọrun mi.”
Explore ORIN DAFIDI 31:14
5
ORIN DAFIDI 31:3
Ìwọ ni àpáta ati ilé ààbò mi; nítorí orúkọ rẹ, máa tọ́ mi kí o sì máa fọ̀nà hàn mí.
Explore ORIN DAFIDI 31:3
6
ORIN DAFIDI 31:5
Ìwọ ni mo fi ẹ̀mí mi lé lọ́wọ́, o ti rà mí pada, OLUWA, Ọlọrun, olóòótọ́.
Explore ORIN DAFIDI 31:5
7
ORIN DAFIDI 31:23
Ẹ fẹ́ràn OLUWA, gbogbo ẹ̀yin olódodo, OLUWA a máa ṣọ́ àwọn olóòótọ́, a sì máa san àlékún ẹ̀san fún àwọn agbéraga.
Explore ORIN DAFIDI 31:23
8
ORIN DAFIDI 31:1
OLUWA, ìwọ ni mo sá di, má jẹ́ kí ojú tì mí lae; gbà mí, nítorí olóòótọ́ ni ọ́.
Explore ORIN DAFIDI 31:1
Home
Bible
Plans
Videos