1
ORIN DAFIDI 36:9
Yoruba Bible
Nítorí pé lọ́dọ̀ rẹ ni orísun ìyè wà; ninu ìmọ́lẹ̀ rẹ ni a ti ń rí ìmọ́lẹ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 36:9
2
ORIN DAFIDI 36:7
Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ níye lórí pupọ, Ọlọrun! Àwọn ọmọ eniyan a máa sá sí abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 36:7
3
ORIN DAFIDI 36:5
OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ga kan ọ̀run; òtítọ́ rẹ sì kan ojú ọ̀run.
Explore ORIN DAFIDI 36:5
4
ORIN DAFIDI 36:6
Òtítọ́ rẹ dàbí òkè ńlá; ìdájọ́ rẹ sì jìn bí ibú omi. OLUWA, àtènìyàn, àtẹranko ni ò ń gbàlà.
Explore ORIN DAFIDI 36:6
Home
Bible
Plans
Videos