1
ORIN DAFIDI 79:9
Yoruba Bible
Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọrun Olùgbàlà wa, nítorí iyì orúkọ rẹ; gbà wá, sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá, nítorí orúkọ rẹ.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 79:9
2
ORIN DAFIDI 79:13
Nígbà náà, àwa eniyan rẹ, àní, àwa agbo aguntan pápá rẹ, yóo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ títí lae; a óo sì máa sọ̀rọ̀ ìyìn rẹ láti ìran dé ìran.
Explore ORIN DAFIDI 79:13
3
ORIN DAFIDI 79:8
Má gbẹ̀san ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńlá wa lára wa; yára, kí o ṣàánú wa, nítorí pé a ti rẹ̀ wá sílẹ̀ patapata.
Explore ORIN DAFIDI 79:8
Home
Bible
Plans
Videos