1
ORIN DAFIDI 8:4
Yoruba Bible
Kí ni eniyan jẹ́, tí o fi n náání rẹ̀? Àní, kí ni ọmọ eniyan, tí o fi ń ṣìkẹ́ rẹ̀?
Compare
Explore ORIN DAFIDI 8:4
2
ORIN DAFIDI 8:3
Nígbà tí mo ṣe akiyesi ojú ọ̀run, iṣẹ́ ọwọ́ rẹ, òṣùpá, ati àwọn ìràwọ̀, tí o sọlọ́jọ̀
Explore ORIN DAFIDI 8:3
3
ORIN DAFIDI 8:5-6
O dá a, ipò rẹ̀ rẹlẹ̀ díẹ̀ sí ti ìwọ Ọlọrun, o sì ti fi ògo ati ọlá dé e ní adé. O mú un jọba lórí àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ, o sì fi gbogbo nǹkan sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀
Explore ORIN DAFIDI 8:5-6
4
ORIN DAFIDI 8:9
OLUWA, Oluwa wa, orúkọ rẹ níyìn pupọ ní gbogbo ayé!
Explore ORIN DAFIDI 8:9
5
ORIN DAFIDI 8:1
OLUWA, Oluwa wa, orúkọ rẹ níyìn pupọ ní gbogbo ayé! Ìwọ ni o gbé ògo rẹ kalẹ̀ lókè ọ̀run.
Explore ORIN DAFIDI 8:1
Home
Bible
Plans
Videos