1
ORIN DAFIDI 9:10
Yoruba Bible
Àwọn tí ó mọ̀ ọ́ yóo gbẹ́kẹ̀lé ọ; nítorí ìwọ, OLUWA, kìí kọ àwọn tí ń wá ọ sílẹ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 9:10
2
ORIN DAFIDI 9:1
OLUWA, tọkàntọkàn ni n óo fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ; n óo ròyìn gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 9:1
3
ORIN DAFIDI 9:9
OLUWA ni ààbò fún àwọn tí a ni lára, òun ni ibi ìsádi ní ìgbà ìpọ́njú.
Explore ORIN DAFIDI 9:9
4
ORIN DAFIDI 9:2
N óo yọ̀, inú mi yóo sì máa dùn nítorí rẹ; n óo kọ orin ìyìn orúkọ rẹ, ìwọ Ọ̀gá-Ògo jùlọ.
Explore ORIN DAFIDI 9:2
5
ORIN DAFIDI 9:8
Yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ ayé, yóo sì fi ẹ̀tọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè.
Explore ORIN DAFIDI 9:8
Home
Bible
Plans
Videos