1
ORIN DAFIDI 81:10
Yoruba Bible
Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín, tí ó mu yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti. Ẹ ya ẹnu yín dáradára, n óo sì bọ yín ní àbọ́yó.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 81:10
2
ORIN DAFIDI 81:13-14
Àwọn eniyan mi ìbá jẹ́ gbọ́ tèmi, àní Israẹli ìbá jẹ́ máa rìn ní ọ̀nà mi! Kíákíá ni èmi ìbá kọjú ìjà sí àwọn ọ̀tá wọn, tí ǹ bá sì ṣẹgun wọn.
Explore ORIN DAFIDI 81:13-14
Home
Bible
Plans
Videos