1
ORIN DAFIDI 82:6
Yoruba Bible
Mo ní, “oriṣa ni yín, gbogbo yín ni ọmọ Ọ̀gá Ògo.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 82:6
2
ORIN DAFIDI 82:3
Ẹ ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn mẹ̀kúnnù ati àwọn ọmọ aláìníbaba; ẹ sì máa ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn tí ojú ń pọ́n ati àwọn talaka.
Explore ORIN DAFIDI 82:3
3
ORIN DAFIDI 82:4
Ẹ gba talaka ati aláìní sílẹ̀, ẹ gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú.”
Explore ORIN DAFIDI 82:4
4
ORIN DAFIDI 82:8
Dìde, Ọlọrun, ṣe ìdájọ́ ayé, nítorí tìrẹ ni gbogbo orílẹ̀-èdè!
Explore ORIN DAFIDI 82:8
Home
Bible
Plans
Videos