1
ORIN DAFIDI 88:1
Yoruba Bible
OLUWA, Ọlọrun, Olùgbàlà mi, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́ ní ọ̀sán; mo ké níwájú rẹ ní òru.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 88:1
2
ORIN DAFIDI 88:2
Jẹ́ kí adura mi dé ọ̀dọ̀ rẹ; tẹ́tí sí igbe mi.
Explore ORIN DAFIDI 88:2
3
ORIN DAFIDI 88:13
Ṣugbọn OLUWA, èmi ń ké pè ọ́; ní òwúrọ̀ n óo gbadura sí ọ.
Explore ORIN DAFIDI 88:13
Home
Bible
Plans
Videos