1
ORIN DAFIDI 89:15
Yoruba Bible
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ó mọ ìhó ayọ̀ nnì, àwọn tí ń rìn ninu ìmọ́lẹ̀ ojurere rẹ, OLUWA
Compare
Explore ORIN DAFIDI 89:15
2
ORIN DAFIDI 89:14
Òdodo ati ẹ̀tọ́ ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ; ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ati òtítọ́ ń lọ ṣiwaju rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 89:14
3
ORIN DAFIDI 89:1
OLUWA, n óo máa kọrin ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ títí lae; n óo máa fi ẹnu mi kéde òtítọ́ rẹ láti ìran dé ìran.
Explore ORIN DAFIDI 89:1
4
ORIN DAFIDI 89:8
OLUWA, Ọlọrun àwọn ọmọ ogun, ta ló lágbára bíi rẹ? OLUWA, òtítọ́ rẹ yí ọ ká.
Explore ORIN DAFIDI 89:8
Home
Bible
Plans
Videos