1
ORIN DAFIDI 97:10
Yoruba Bible
Ẹ̀yin tí ẹ fẹ́ràn OLUWA, ẹ kórìíra ibi; OLUWA á máa dá ẹ̀mí àwọn olùfọkànsìn rẹ̀ sí, a sì máa gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 97:10
2
ORIN DAFIDI 97:12
Ẹ máa yọ̀ ninu OLUWA, ẹ̀yin olódodo, kí ẹ sì máa yin orúkọ mímọ́ rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 97:12
3
ORIN DAFIDI 97:11
Ìmọ́lẹ̀ á máa tàn fún àwọn olódodo, ayọ̀ sì wà fún àwọn olótìítọ́ inú.
Explore ORIN DAFIDI 97:11
4
ORIN DAFIDI 97:9
Nítorí ìwọ OLUWA ni Ọ̀gá Ògo, o ju gbogbo ayé lọ, a gbé ọ ga ju gbogbo oriṣa lọ.
Explore ORIN DAFIDI 97:9
Home
Bible
Plans
Videos