1
ORIN DAFIDI 96:4
Yoruba Bible
Nítorí OLUWA tóbi, ó yẹ kí á máa yìn ín lọpọlọpọ; ó sì yẹ kí á bẹ̀rù rẹ̀ ju gbogbo oriṣa lọ.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 96:4
2
ORIN DAFIDI 96:2
Ẹ kọ orin sí OLUWA, ẹ yin orúkọ rẹ̀; ẹ sọ nípa ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́.
Explore ORIN DAFIDI 96:2
3
ORIN DAFIDI 96:1
Ẹ kọ orin titun sí OLUWA; gbogbo ayé, ẹ kọ orin sí OLUWA.
Explore ORIN DAFIDI 96:1
4
ORIN DAFIDI 96:3
Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; ẹ sọ̀rọ̀ iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan.
Explore ORIN DAFIDI 96:3
5
ORIN DAFIDI 96:9
Ẹ sin OLUWA ninu ẹwà ìwà mímọ́; gbogbo ayé, ẹ wárìrì níwájú rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 96:9
Home
Bible
Plans
Videos