1
Owe 25:28
Bibeli Mimọ
Ẹniti kò le ṣe akoso ara rẹ̀, o dabi ilu ti a wo lulẹ, ti kò si li odi.
Compare
Explore Owe 25:28
2
Owe 25:21-22
Bi ebi ba npa ọta rẹ, fun u li onjẹ; bi ongbẹ ba si gbẹ ẹ, fun u li ohun mimu. Nitoriti iwọ o kó ẹyin iná jọ si ori rẹ̀, Oluwa yio san fun ọ.
Explore Owe 25:21-22
Home
Bible
Plans
Videos