1
Owe 26:4-5
Bibeli Mimọ
Máṣe da aṣiwère lohùn gẹgẹ bi wère rẹ̀, ki iwọ pãpa ki o má ba dabi rẹ̀. Da aṣiwère lohùn gẹgẹ bi wère rẹ̀, ki on ki o má ba gbọ́n li oju ara rẹ̀.
Compare
Explore Owe 26:4-5
2
Owe 26:11
Bi aja ti ipada sinu ẽbì rẹ̀, bẹ̃li aṣiwère itun pada sinu wère rẹ̀.
Explore Owe 26:11
3
Owe 26:20
Nigbati igi tan, ina a kú, bẹ̃ni nigbati olofofo kò si, ìja a da.
Explore Owe 26:20
4
Owe 26:27
Ẹnikẹni ti o ba wà ihò yio ṣubu sinu rẹ̀: ẹniti o ba si nyi okuta, on ni yio pada tọ̀.
Explore Owe 26:27
5
Owe 26:12
Iwọ ri ẹnikan ti o gbọ́n li oju ara rẹ̀? ireti mbẹ fun aṣiwère jù fun u lọ.
Explore Owe 26:12
6
Owe 26:17
Ẹniti nkọja lọ, ti o si dasi ìja ti kì iṣe tirẹ̀, o dabi ẹniti o mu ajá leti.
Explore Owe 26:17
Home
Bible
Plans
Videos