1
O. Daf 12:6
Bibeli Mimọ
Ọ̀rọ Oluwa, ọ̀rọ funfun ni, bi fadaka ti a yọ́ ni ileru erupẹ, ti a dà ni igba meje.
Compare
Explore O. Daf 12:6
2
O. Daf 12:7
Iwọ o pa wọn mọ́, Oluwa, iwọ o pa olukuluku wọn mọ́ kuro lọwọ iran yi lailai.
Explore O. Daf 12:7
3
O. Daf 12:5
Nitori inira awọn talaka, nitori imi-ẹ̀dun awọn alaini, Oluwa wipe, nigbayi li emi o dide; emi o si yọ ọ si ibi ailewu kuro lọwọ ẹniti nfẹ̀ si i.
Explore O. Daf 12:5
Home
Bible
Plans
Videos