1
O. Daf 13:5
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn emi o gbẹkẹle ãnu rẹ; ọkàn mi yio yọ̀ ni igbala rẹ.
Compare
Explore O. Daf 13:5
2
O. Daf 13:6
Emi o ma kọrin si Oluwa, nitoriti o ṣe fun mi li ọ̀pọlọpọ.
Explore O. Daf 13:6
3
O. Daf 13:1
IWỌ o ti gbagbe mi pẹ to, Oluwa, lailai? iwọ o ti pa oju rẹ mọ́ pẹ to kuro lara mi?
Explore O. Daf 13:1
4
O. Daf 13:2
Emi o ti ma gbìmọ li ọkàn mi pẹ to? ti emi o ma ni ibinujẹ li ọkàn mi lojojumọ? ọta mi yio ti gberaga sori mi pẹ to?
Explore O. Daf 13:2
Home
Bible
Plans
Videos