1
O. Daf 137:1
Bibeli Mimọ
LI ẹba odò Babeli, nibẹ li awa gbe joko, awa si sọkun nigbati awa ranti Sioni.
Compare
Explore O. Daf 137:1
2
O. Daf 137:3-4
Nitoripe nibẹ li awọn ti o kó wa ni igbekun bère orin lọwọ wa; ati awọn ti o ni wa lara bère idaraya wipe; Ẹ kọ orin Sioni kan fun wa. Awa o ti ṣe kọ orin Oluwa ni ilẹ àjeji?
Explore O. Daf 137:3-4
Home
Bible
Plans
Videos