1
O. Daf 138:7
Bibeli Mimọ
Bi emi tilẹ nrìn ninu ipọnju, iwọ ni yio sọ mi di ãye: iwọ o nà ọwọ rẹ si ibinu awọn ọta mi, ọwọ ọtún rẹ yio si gbà mi.
Compare
Explore O. Daf 138:7
2
O. Daf 138:3
Li ọjọ ti mo kepè, iwọ da mi lohùn, iwọ si fi ipa mu mi lara le li ọkàn mi.
Explore O. Daf 138:3
3
O. Daf 138:1
EMI o ma yìn ọ tinu-tinu mi gbogbo; niwaju awọn oriṣa li emi o ma kọrin iyìn si ọ.
Explore O. Daf 138:1
Home
Bible
Plans
Videos