1
O. Daf 139:14
Bibeli Mimọ
Emi o yìn ọ; nitori tẹ̀ru-tẹ̀ru ati tiyanu-tiyanu li a dá mi: iyanu ni iṣẹ rẹ; eyinì li ọkàn mi si mọ̀ dajudaju.
Compare
Explore O. Daf 139:14
2
O. Daf 139:23-24
Ọlọrun, wadi mi, ki o si mọ̀ aiya mi: dán mi wò, ki o si mọ̀ ìro-inu mi: Ki o si wò bi ipa-ọ̀na buburu kan ba wà ninu mi, ki o si fi ẹsẹ mi le ọ̀na ainipẹkun.
Explore O. Daf 139:23-24
3
O. Daf 139:13
Nitori iwọ li o dá ọkàn mi: iwọ li o bò mi mọlẹ ni inu iya mi.
Explore O. Daf 139:13
4
O. Daf 139:16
Oju rẹ ti ri ohun ara mi ti o wà laipé: a ti ninu iwe rẹ ni a ti kọ gbogbo wọn si, li ojojumọ li a nda wọn, nigbati ọkan wọn kò ti isi.
Explore O. Daf 139:16
5
O. Daf 139:1
OLUWA, iwọ ti wadi mi, iwọ si ti mọ̀ mi.
Explore O. Daf 139:1
6
O. Daf 139:7
Nibo li emi o gbe lọ kuro lọwọ ẹmi rẹ? tabi nibo li emi o sárè kuro niwaju rẹ?
Explore O. Daf 139:7
7
O. Daf 139:2
Iwọ mọ̀ ijoko mi ati idide mi, iwọ mọ̀ iro mi li ọ̀na jijin rére.
Explore O. Daf 139:2
8
O. Daf 139:4
Nitori ti kò si ọ̀rọ kan li ahọn mi, kiyesi i, Oluwa, iwọ mọ̀ ọ patapata.
Explore O. Daf 139:4
9
O. Daf 139:3
Iwọ yi ipa ọ̀na mi ká ati ibulẹ mi, gbogbo ọ̀na mi si di mimọ̀ fun ọ.
Explore O. Daf 139:3
Home
Bible
Plans
Videos