1
O. Daf 140:13
Bibeli Mimọ
Nitõtọ awọn olododo yio ma fi ọpẹ fun orukọ rẹ: awọn ẹni diduro-ṣinṣin yio ma gbe iwaju rẹ.
Compare
Explore O. Daf 140:13
2
O. Daf 140:1-2
OLUWA gbà mi lọwọ ọkunrin buburu nì, yọ mi lọwọ ọkunrin ìka nì; Ẹniti nrò ìwa-buburu ni inu wọn; nigbagbogbo ni nwọn nrú ìja soke si mi.
Explore O. Daf 140:1-2
3
O. Daf 140:12
Emi mọ̀ pe, Oluwa yio mu ọ̀ran olupọnju duro, ati are awọn talaka.
Explore O. Daf 140:12
4
O. Daf 140:4
Oluwa, pa mi mọ́ kuro lọwọ enia buburu; yọ mi kuro lọwọ ọkunrin ìka nì; ẹniti o ti pinnu rẹ̀ lati bì ìrin mi ṣubu.
Explore O. Daf 140:4
Home
Bible
Plans
Videos