1
O. Daf 149:4
Bibeli Mimọ
YBCV
Nitori ti Oluwa ṣe inudidùn si awọn enia rẹ̀; yio fi igbala ṣe awọn onirẹlẹ li ẹwà.
Compare
Explore O. Daf 149:4
2
O. Daf 149:6
Ki iyìn Ọlọrun ki o wà li ẹnu wọn, ati idà oloju meji li ọwọ wọn
Explore O. Daf 149:6
3
O. Daf 149:1
Ẹ fi iyìn fun Oluwa. Ẹ kọ orin titun si Oluwa, ati iyìn rẹ̀ ninu ijọ awọn enia-mimọ́.
Explore O. Daf 149:1