1
O. Daf 150:6
Bibeli Mimọ
YBCV
Jẹ ki ohun gbogbo ti o li ẹmi ki o yìn Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.
Compare
Explore O. Daf 150:6
2
O. Daf 150:1
Ẹ fi iyìn fun Oluwa. Ẹ fi iyìn fun Ọlọrun ninu ibi mimọ́ rẹ̀; yìn i ninu ofurufu oju-ọrun agbara rẹ̀.
Explore O. Daf 150:1
3
O. Daf 150:2
Yìn i nitori iṣẹ agbara rẹ̀: yìn i gẹgẹ bi titobi nla rẹ̀.
Explore O. Daf 150:2