1
Òwe 17:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọ̀rẹ́ a máa fẹ́ni nígbà gbogbo, arákùnrin sì wà fún ìgbà ìpọ́njú.
Compare
Explore Òwe 17:17
2
Òwe 17:22
Ọkàn tí ó túká jẹ́ oògùn gidi, ṣùgbọ́n ọkàn tí ó bàjẹ́ a máa mú kí egungun gbẹ.
Explore Òwe 17:22
3
Òwe 17:9
Ẹni tí ó fojú fo ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ ẹ́ mú kí ìfẹ́ gbòòrò sí i. Ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ń tẹnumọ́ ọ̀rọ̀ yóò pín ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ méjì ní yà.
Explore Òwe 17:9
4
Òwe 17:27
Ènìyàn tó ní ìmọ̀ máa ń ṣọ́ra fún àwọn ọ̀rọ̀ tí ó ń sọ, ènìyàn olóye sì máa ń ní sùúrù.
Explore Òwe 17:27
5
Òwe 17:28
Kódà aláìgbọ́n máa ń dàbí ọlọ́gbọ́n bí ó bá dákẹ́ àti bí olóye bí ó bá fètèmétè.
Explore Òwe 17:28
6
Òwe 17:1
Òkèlè gbígbẹ tòun tàlàáfíà àti ìdákẹ́ jẹ́ẹ́ sàn ju ilé tí ó kún fọ́fọ́ fún ẹran àti ìjà.
Explore Òwe 17:1
7
Òwe 17:14
Bíbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí ẹni tí ó dá ojú fún adágún omi nítorí náà mẹ́nu kúrò nínú ọ̀rọ̀ kí ó tó di ìjà.
Explore Òwe 17:14
8
Òwe 17:15
Gbígbé ẹ̀bi fún aláre àti dídá ẹni jàre lẹ́bi, OLúWA kórìíra méjèèjì.
Explore Òwe 17:15
Home
Bible
Plans
Videos