1
Òwe 18:21
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ikú àti ìyè ń bẹ nípa ahọ́n wọn, àwọn tí ó sì fẹ́ràn rẹ̀ yóò jẹ ẹ́.
Compare
Explore Òwe 18:21
2
Òwe 18:10
Orúkọ OLúWA, ilé ìṣọ́ agbára ni; olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ìgbàlà.
Explore Òwe 18:10
3
Òwe 18:24
Ènìyàn tí ó ní ọ̀rẹ́ púpọ̀ le è parun ṣùgbọ́n ọ̀rẹ́ kan wà tí ó súnmọ́ ni tímọ́tímọ́ ju arákùnrin.
Explore Òwe 18:24
4
Òwe 18:22
Ẹni tí ó rí aya fẹ́, rí ohun rere, o sì gba ojúrere lọ́dọ̀ OLúWA.
Explore Òwe 18:22
5
Òwe 18:13
Ẹni tí ó ń fèsì kí ó tó gbọ́, èyí ni ìwà òmùgọ̀ àti ìtìjú rẹ̀.
Explore Òwe 18:13
6
Òwe 18:2
Aláìgbọ́n kò rí inú dídùn sí òye ṣùgbọ́n ó ní inú dídùn sí sísọ èrò tirẹ̀.
Explore Òwe 18:2
7
Òwe 18:12
Ṣáájú ìṣubú ọkàn ènìyàn a kọ́kọ́ máa gbéraga ṣùgbọ́n ìrẹ̀lẹ̀ ni ó máa ń ṣáájú ọlá.
Explore Òwe 18:12
Home
Bible
Plans
Videos