1
Òwe 19:21
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ète inú ọkàn ènìyàn ṣùgbọ́n ìfẹ́ OLúWA ní ó máa ń borí.
Compare
Explore Òwe 19:21
2
Òwe 19:17
Ẹni tí ó ṣàánú tálákà, OLúWA ní ó yá yóò sì pín in lérè ohun tí ó ti ṣe.
Explore Òwe 19:17
3
Òwe 19:11
Ọgbọ́n ènìyàn a máa fún un ní sùúrù; fún ògo rẹ̀ ni láti fojú fo àṣìṣe dá.
Explore Òwe 19:11
4
Òwe 19:20
Fetí sí ìmọ̀ràn kí o sì gba ẹ̀kọ́ ní ìgbẹ̀yìn gbẹ́yín ìwọ yóò di ọlọ́gbọ́n.
Explore Òwe 19:20
5
Òwe 19:23
Ìbẹ̀rù OLúWA ń mú ìyè wá: nígbà náà ọkàn ń balẹ̀, láìsí ewu.
Explore Òwe 19:23
6
Òwe 19:8
Ẹni tí ó gba ọgbọ́n fẹ́ràn ọkàn ara rẹ̀; ẹni tí ó bá káràmáṣìkí òye yóò gbèrú.
Explore Òwe 19:8
7
Òwe 19:18
Bá ọmọ rẹ wí nítorí nínú ìyẹn ni ìrètí wà; àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ lọ́wọ́ nínú ìparun un rẹ̀.
Explore Òwe 19:18
8
Òwe 19:9
Ajẹ́rìí èké kì yóò lọ láìjìyà ẹni tí ó sì ń tú irọ́ jáde yóò parun.
Explore Òwe 19:9
Home
Bible
Plans
Videos