1
Saamu 141:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Fi ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ ẹnu mi, OLúWA: kí o sì máa pa ìlẹ̀kùn ètè mi mọ́.
Compare
Explore Saamu 141:3
2
Saamu 141:4
Má ṣe jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ohun tí ń ṣe ibi, Láti máa bá àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ búburú má sì ṣe jẹ́ kí èmi jẹ àdídùn wọn.
Explore Saamu 141:4
3
Saamu 141:1-2
OLúWA, èmi ké pè ọ́; yára wá sí ọ̀dọ̀ mi. Gbọ́ ohùn mi, nígbà tí mo bá ń ké pè ọ́. Jẹ́ kí àdúrà mi ó wá sí iwájú rẹ bí ẹbọ tùràrí àti ìgbé ọwọ́ mi si òkè rí bí ẹbọ àṣálẹ́.
Explore Saamu 141:1-2
Home
Bible
Plans
Videos