1
Saamu 142:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi kígbe sí ọ, OLúWA: èmi wí pé, “ìwọ ni ààbò mi, ìpín mi ní ilẹ̀ alààyè.”
Compare
Explore Saamu 142:5
2
Saamu 142:7
Mú ọkàn mi jáde kúrò nínú túbú, kí èmi lè máa yin orúkọ rẹ. Nígbà náà ni àwọn olódodo yóò yí mi káàkiri nítorí ìwọ yóò fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn ba mi ṣe.
Explore Saamu 142:7
3
Saamu 142:3
Nígbà tí ẹ̀mí mi ṣàárẹ̀ nínú mi, ìwọ ni ẹni tí ó mọ ọ̀nà mi. Ní ipa ọ̀nà tí èmi ń rìn ènìyàn ti dẹ okùn fún mi ní ìkọ̀kọ̀
Explore Saamu 142:3
4
Saamu 142:1
Èmi kígbe sókè sí OLúWA; Èmi gbé ohùn mi sókè sí OLúWA fún àánú.
Explore Saamu 142:1
5
Saamu 142:6
Fi etí sí igbe mi, nítorí tí èmi wà nínú àìnírètí gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi, nítorí wọ́n lágbára jù mí lọ
Explore Saamu 142:6
Home
Bible
Plans
Videos