1
Saamu 4:8
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi yóò dùbúlẹ̀, èmi ó sì sùn ní àlàáfíà, nítorí ìwọ nìkan, OLúWA, ni o mú mi gbé láìléwu.
Compare
Explore Saamu 4:8
2
Saamu 4:4
Ẹ bínú ẹ má ṣe ṣẹ̀; Nígbà tí ẹ bá wà lórí ibùsùn yín, ẹ bá ọkàn yín sọ̀rọ̀, kí ó sì dákẹ́ jẹ́.
Explore Saamu 4:4
3
Saamu 4:1
Dá mi lóhùn nígbà tí mo bá pè ọ́, ìwọ Ọlọ́run òdodo mi, Fún mi ní ìdáǹdè nínú ìpọ́njú mi; ṣàánú fún mi, kí o sì gbọ́ àdúrà mi.
Explore Saamu 4:1
Home
Bible
Plans
Videos