1
Saamu 5:12
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Dájúdájú, OLúWA, ìwọ bùkún olódodo; ìwọ fi ojúrere rẹ yí wọn ká bí asà.
Compare
Explore Saamu 5:12
2
Saamu 5:3
Ní òwúrọ̀, OLúWA, ìwọ yóò gbọ́ ohùn mi; ní òwúrọ̀, èmi yóò gbé ẹ̀bẹ̀ mi sí iwájú rẹ̀ èmi yóò sì dúró ní ìrètí.
Explore Saamu 5:3
3
Saamu 5:11
Ṣùgbọ́n, jẹ́ kí gbogbo àwọn tí ó sádi ọ́ kí ó yọ̀; jẹ kí wọn máa kọrin fún ayọ̀ títí. Tan ààbò rẹ sórí wọn, àti àwọn tí ó fẹ́ràn orúkọ rẹ yóò máa yọ̀ nínú rẹ.
Explore Saamu 5:11
4
Saamu 5:8
Tọ́ mi, OLúWA, nínú òdodo rẹ, nítorí àwọn ọ̀tá mi, mú ọ̀nà rẹ tọ́ níwájú mi.
Explore Saamu 5:8
5
Saamu 5:2
Fi etí sílẹ̀ sí igbe mi fún ìrànlọ́wọ́, ọba mi àti Ọlọ́run mi, nítorí ìwọ ni mo gba àdúrà sí.
Explore Saamu 5:2
Home
Bible
Plans
Videos