YouVersion Logo
Search Icon

Ìṣe àwọn Aposteli 1:8

Ìṣe àwọn Aposteli 1:8 YCB

Ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò gba agbára, nígbà tí Ẹ̀mí Mímọ́ bá bà lé e yín: ẹ̀yin yóò sì máa ṣe ẹlẹ́rìí mi ni Jerusalẹmu, àti ní gbogbo Judea, àti ní Samaria, àti títí dé òpin ilẹ̀ ayé.”

Video for Ìṣe àwọn Aposteli 1:8