1
Joh 3:16
Bibeli Mimọ
Nitori Ọlọrun fẹ araiye tobẹ̃ gẹ, ti o fi Ọmọ bíbi rẹ̀ kanṣoṣo funni, ki ẹnikẹni ti o ba gbà a gbọ́ má bà ṣegbé, ṣugbọn ki o le ni ìye ainipẹkun.
Compara
Explorar Joh 3:16
2
Joh 3:17
Nitori Ọlọrun kò rán Ọmọ rẹ̀ si aiye lati da araiye lẹjọ; ṣugbọn ki a le ti ipasẹ rẹ̀ gbà araiye là.
Explorar Joh 3:17
3
Joh 3:3
Jesu dahùn o si wi fun u pe, Lõtọ, lõtọ ni mo wi fun ọ, Bikoṣepe a tún enia bí, on kò le ri ijọba Ọlọrun.
Explorar Joh 3:3
4
Joh 3:18
Ẹniti o ba gbà a gbọ́, a ko ni da a lẹjọ; ṣugbọn a ti da ẹniti kò gbà a gbọ́ lẹjọ na, nitoriti kò gbà orukọ Ọmọ bíbi kanṣoṣo ti Ọlọrun gbọ́.
Explorar Joh 3:18
5
Joh 3:19
Eyi ni idajọ na pe, imọlẹ wá si aiye, awọn enia si fẹ òkunkun jù imọlẹ lọ, nitoriti iṣẹ wọn buru.
Explorar Joh 3:19
6
Joh 3:30
On kò le ṣaima pọsi i, ṣugbọn emi kò le ṣaima rẹ̀hin.
Explorar Joh 3:30
7
Joh 3:20
Nitori olukuluku ẹniti o ba hùwa buburu ni ikorira imọlẹ, ki isi wá si imọlẹ, ki a máṣe ba iṣẹ rẹ̀ wí.
Explorar Joh 3:20
8
Joh 3:36
Ẹniti o ba gbà Ọmọ gbọ́, o ni iye ainipẹkun: ẹniti kò ba si gbà Ọmọ gbọ, kì yio ri ìye; ṣugbọn ibinu Ọlọrun mbẹ lori rẹ̀.
Explorar Joh 3:36
9
Joh 3:14
Bi Mose si ti gbé ejò soke li aginjù, gẹgẹ bẹ̃li a kò le ṣe alaigbé Ọmọ-enia soke pẹlu
Explorar Joh 3:14
10
Joh 3:35
Baba fẹ Ọmọ, o si ti fi ohun gbogbo le e lọwọ.
Explorar Joh 3:35
Inici
La Bíblia
Plans
Vídeos