1
Gẹnẹsisi 11:6-7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA wí pé, “Bí àwọn ènìyàn bá ń jẹ́ ọ̀kan àti èdè kan tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe iṣẹ́ yìí, kò sí ohun tí wọ́n gbèrò tí wọn kò ní le ṣe yọrí. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a sọ̀kalẹ̀ lọ, kí a da èdè wọn rú kí èdè wọn má ba à yé ara wọn mọ́.”
Համեմատել
Ուսումնասիրեք Gẹnẹsisi 11:6-7
2
Gẹnẹsisi 11:4
Nígbà náà ni wọ́n wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a tẹ ìlú kan dó fún ara wa, kí a sì kọ́ ilé ìṣọ́ kan tí yóò kan ọ̀run, kí a ba à lè ní orúkọ (òkìkí) kí a má sì tú káàkiri sórí gbogbo ilẹ̀ ayé.”
Ուսումնասիրեք Gẹnẹsisi 11:4
3
Gẹnẹsisi 11:9
Ìdí èyí ni a fi pè é ní Babeli nítorí ní ibẹ̀ ni Ọlọ́run ti da èdè gbogbo ayé rú, tí ó sì tú àwọn ènìyàn ká sí gbogbo orí ilẹ̀ ayé.
Ուսումնասիրեք Gẹnẹsisi 11:9
4
Gẹnẹsisi 11:1
Lẹ́yìn náà, gbogbo àgbáyé sì ń sọ èdè kan ṣoṣo.
Ուսումնասիրեք Gẹnẹsisi 11:1
5
Gẹnẹsisi 11:5
Ṣùgbọ́n, OLúWA sọ̀kalẹ̀ láti wo ìlú àti ilé ìṣọ́ tí àwọn ènìyàn náà ń kọ́.
Ուսումնասիրեք Gẹnẹsisi 11:5
6
Gẹnẹsisi 11:8
Ọlọ́run sì tú wọn ká sórí ilẹ̀ gbogbo, wọ́n sì ṣíwọ́ ìlú náà tí wọn ń tẹ̀dó.
Ուսումնասիրեք Gẹnẹsisi 11:8
Գլխավոր
Աստվածաշունչ
Ծրագրեր
Տեսանյութեր