1
Gẹn 5:24
Bibeli Mimọ
Enoku si ba Ọlọrun rìn: on kò si sí; nitori ti Ọlọrun mu u lọ.
Porovnať
Preskúmať Gẹn 5:24
2
Gẹn 5:22
Enoku si ba Ọlọrun rìn li ọ̃dunrun ọdún lẹhin ti o bì Metusela, o si bí ọmọkunrin ati ọmọbinrin
Preskúmať Gẹn 5:22
3
Gẹn 5:1
EYI ni iwe iran Adamu: Li ọjọ́ ti Ọlọrun dá ọkunrin, li aworan Ọlọrun li o dá a.
Preskúmať Gẹn 5:1
4
Gẹn 5:2
Ati akọ ati abo li o dá wọn; o si súre fun wọn, o si pè orukọ wọn ni Adamu, li ọjọ́ ti a dá wọn.
Preskúmať Gẹn 5:2
Domov
Biblia
Plány
Videá