1
Gẹnẹsisi 10:8
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.
Linganisha
Chunguza Gẹnẹsisi 10:8
2
Gẹnẹsisi 10:9
Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú OLúWA; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú OLúWA.”
Chunguza Gẹnẹsisi 10:9
Nyumbani
Biblia
Mipango
Video