1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:59-60
Yoruba Bible
Bí wọ́n ti ń sọ òkúta lu Stefanu, ó ké pe Jesu Oluwa, ó ní, “Oluwa Jesu, gba ẹ̀mí mi.” Ni ó bá kúnlẹ̀, ó kígbe, ó ní, “Oluwa, má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn lọ́rùn.” Nígbà tí ó sọ báyìí tán, ó kú.
موازنہ
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:59-60
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:49
‘Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé ni tìmùtìmù ìtìsẹ̀ mi. Irú ilé wo ni ẹ̀ báà kọ́ fún mi? Bẹ́ẹ̀ ni Oluwa wí. Níbo ni ẹ̀ báà palẹ̀ mọ́ fún mi pé kí n ti máa sinmi?
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:49
3
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:57-58
Ni wọ́n bá kígbe, wọ́n fi ọwọ́ di etí, gbogbo wọ́n rọ́ lù ú; wọ́n fà á jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú, wọ́n bá ń sọ ọ́ ní òkúta. Àwọn ẹlẹ́rìí fi ẹ̀wù wọn lélẹ̀ níwájú ọdọmọkunrin kan tí à ń pè ní Saulu.
تلاش ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 7:57-58
صفحہ اول
بائبل
مطالعاتی منصوبہ
Videos