ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:6
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 3:6 YCE
Peteru bá sọ fún un pé, “N kò ní fadaka tabi wúrà, ṣugbọn n óo fún ọ ní ohun tí mo ní. Ní orúkọ Jesu Kristi ti Nasarẹti, máa rìn.”