YouVersion Logo
تلاش

JOHANU 20:27-28

JOHANU 20:27-28 YCE

Ó wá wí fún Tomasi pé, “Mú ìka rẹ wá, wo ọwọ́ mi, mú ọwọ́ rẹ wá kí o fi kan ẹ̀gbẹ́ mi. Má ṣe alaigbagbọ mọ́, ṣugbọn gbàgbọ́.” Tomasi dá a lóhùn pé, “Oluwa mi ati Ọlọrun mi!”

پڑھیں JOHANU 20