← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú II. Tim 4:7
Ifarafun Oore-ọ̀fẹ́
3 Awọn ọjọ
Oore-ọ̀fẹ́ jẹ́ ẹ̀bùn Ọlọ́run tí kòdá lórí ohunkóhun tí a ṣe tàbí tóṣe. ó mú wa tọ́ lojú Ọlọ́run. Nípa rẹ̀ ni a gbàwá là. Nípa rẹ̀ lafi lè béèrè ìdáríjì. Kòwà k’ẹ̀ṣẹ̀ máa pọ̀sí. Kìí ṣ’èrè ohun rere tí a ṣe, kò sẹ́ni tí ó lè fọ́nnu nípa rẹ̀. A mọ́ pé ìrìn pẹ̀lú Ọlọ́run kìí ṣe nípa ipá tàbí agbára ṣùgbọ́n nípa oore-ọ̀fẹ́. Oore-ọ̀fẹ́ yìí tó fún wa.