
Ohun èlò tí Bíbélì
100% lọ́fẹ̀ẹ́. Kò sí ìpolówó tàbí ìrajà kankan.



Àwọn ìtàn ti Ìyípadà Ìgbésí ayé

Éríkà, láti USA
"Ogun olóró jè bárakú fún mi fún ọdún 10 tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, mo sì pàdánù ohun gbogbo… Fún bí ọdún méjì báyìí, mo ti rí ìyípadà nínú ayémi tí ó mú mi gbà pé Jésù nìkan ni ó ṣe é."Kàá Síwájú →
Omri, láti ìlú Filipínì
Mo ń ka Ètò òbí tí ó níwà-bí-Ọlọ́run àti Ètò ọkọ oníwà-bí-Ọlọ́run. Ohun Èlò Bíbélì jẹ́ kí ó ṣeé ṣe fún mi láti lo èkó Bíbélì ní gbogbo ìgbésí ayé mi.Kàá Síwájú →
Todd, lati USA
“Màmá mi lo fi ohun èlò Bíbélì hàn mí. Ó ti ń kojú àwọn ìṣòro kọ̀ọ̀kan. Mo pinnu láti gbìyànjú rẹ̀ wò, láti ìgbà náà wá, ìgbésí ayé mi ti yípadà pátápátá.”Kàá Síwájú →
Àwon ẹ̀yà
Àwọn ìtumọ̀ Bíbélì tí ó gbẹ́kẹ̀lé ní èdè rẹ.
YBCV
Bibeli Mimọ
BMYO
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCE
Yoruba Bible
KJV
King James Version

Ohùn
Tẹ́ etí sí Bíbélì ní ibikíbi tí o bá lọ.


Bẹ̀ẹ̀rẹ̀ Ọjọ́ Rẹ Ní Ọ̀nà Tí Ó Tọ́
Gba ẹsẹ̀ Bíbélì tuntun, ìwàásù kúkúrú, àti Àdúrà Ìtọ́ni ní ojoojúmọ́.


Àwọn Ètò
Kọ́ ìṣe Bíbélì pẹ̀lú àwọn Ètò ojoojúmọ́.








Sàwárí
Wá àwọn ẹsẹ̀, ètò, àti àwọn fídíò fún èyíkéyìí kókó-ọ̀rọ̀.


Jẹ́ kí Bíbélì jẹ́ TìRẹ́
Ṣe àṣàrò bí o ṣe ń ka àwọn ohun tí ọ ti ṣe Ààmì sí, àwọn àkọsílẹ̀, àti àwọn irinṣẹ́ míràn tí ó wúlò.

Ṣe ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò Bíbélì Mímọ́
Máa ka Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lójoojúmọ́.
