Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní

1 Oṣù Òkúdu 2026

Eksodu 14:14 - OLúWA yóò jà fún un yín; kí ẹ̀yin kí ó sá à mu sùúrù.”
Pín
OLúWA yóò jà fún un yín; kí ẹ̀yin kí ó sá à mu sùúrù.”

Eksodu 14:14 (BMYO)

Kà Eksodu 14:14
Fọwọ́ síi

Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó wà fún ọ̀sẹ̀ yìí

31 Oṣù Ẹ̀bibi 2026

“Ìbẹ̀rù OLúWA ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n, ìmọ̀ nípa Ẹni Mímọ́ ni òye.

Òwe 9:10 (BMYO)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 31 Oṣù Ẹ̀bibi 2026 - àwòrán 0

30 Oṣù Ẹ̀bibi 2026

Ẹ jẹ́ ọlọ́gbọ́n ní ti bí ẹ ti ń ṣe pẹ̀lú àwọn tí ń bẹ lóde, kí ẹ sì máa ṣe ṣí àǹfààní tí ẹ bá nílò. Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yín kí ó dàpọ̀ mọ́ oore-ọ̀fẹ́ nígbà gbogbo, èyí tí a fi iyọ̀ dùn, kí ẹ̀yin kí ó le mọ́ bí ẹ̀yin ó tí máa dá olúkúlùkù ènìyàn lóhùn.

Kolose 4:5-6 (BMYO)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 30 Oṣù Ẹ̀bibi 2026 - àwòrán 1

29 Oṣù Ẹ̀bibi 2026

Nítorí náà, ẹ tẹríba fún Ọlọ́run. Ẹ kọ ojú ìjà sí èṣù, òun ó sì sá kúrò lọ́dọ̀ yín.

Jakọbu 4:7 (BMYO)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 29 Oṣù Ẹ̀bibi 2026 - àwòrán 2

28 Oṣù Ẹ̀bibi 2026

Olùbùkún ni OLúWA, Ọlọ́run Olùgbàlà wa, ẹni tí ó ń fi ojoojúmọ́ gba ẹrù wa rù. Sela.

Saamu 68:19 (BMYO)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 28 Oṣù Ẹ̀bibi 2026 - àwòrán 3

27 Oṣù Ẹ̀bibi 2026

Ẹ má ṣe ṣe àníyàn ohunkóhun; ṣùgbọ́n nínú ohun gbogbo, nípa àdúrà àti ẹ̀bẹ̀ pẹ̀lú ìdúpẹ́, ẹ máa fi ìbéèrè yín hàn fún Ọlọ́run.

Filipi 4:6 (BMYO)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 27 Oṣù Ẹ̀bibi 2026 - àwòrán 4

26 Oṣù Ẹ̀bibi 2026

Ẹnikẹ́ni tí ó ṣọ́ ẹnu rẹ̀ pa ẹnu ara rẹ̀ mọ́, ṣùgbọ́n ẹni tí ó ń sọ̀rọ̀ gbàù gbàù yóò parun.

Òwe 13:3 (BMYO)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 26 Oṣù Ẹ̀bibi 2026 - àwòrán 5
Ṣe Ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò náà

Gba Bíbélì ọ̀fẹ́ ti orí ayélujára fún fóònù àti tábúlẹ̀tì.

Gbá ohun èlò ti Bíbélì ìsisìyíwàyí
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
Yorùbá

©2026 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest