O. Daf 68:19
O. Daf 68:19 Bibeli Mimọ (YBCV)
Olubukún li Oluwa, ẹni ti o nba wa gbé ẹrù wa lojojumọ; Ọlọrun ni igbala wa.
Pín
Kà O. Daf 68O. Daf 68:19 Yoruba Bible (YCE)
Ìyìn ni fún OLUWA, Ọlọrun ìgbàlà wa, tí ń bá wa gbé ẹrù wa lojoojumọ.
Pín
Kà O. Daf 68