← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Iṣe Apo 11:23
ỌGBỌ́N
3 Awọn ọjọ
Kìí ṣe pé ìgbé ayé onígbàgbọ́ ní ọ̀nà kan pàtó tí ó ń gbà ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí ó ti gba Krístì. Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé a jẹ́ ti Krístì, a ṣì wà nínú ayé yìí (Jòhánù 17:16). ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àlàkalẹ̀ nílò ìmúyàtọ̀ tí ó mú ìdọ́gba bá wíwà wa lójúkorojú nínú ayé pẹ̀lú ìdámọ̀ wa nípa ẹ̀mí. Bíi ẹ̀dá ti ẹ̀mí, a gbọ́dọ̀ ṣe bó ti tọ́.