← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Efe 4:27
Ìbínú
Ọjọ́ Mẹ́ta
Gbogbo wa la máa n bínú! Ìdáhùn rẹ sí ìbínú dá lórí gbígbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run àti ṣíṣàrò lórí Ọ̀rọ Rẹ̀. Wo ètò kíkà Ìgbẹ́kẹ̀lé lẹ́gbẹ̀ẹ́ àkọ́lé Ìbínú. Àwọn ẹsẹ̀ tí ó tẹ̀lé e, tí a bá fi wọ́n ṣe àkọ́sórí, lè ràn ọ́ l'ọ́wọ́ láti dáhùn sí ìbínú l'ọ́na tó tọ́. Jẹ́ kí ìgbésí ayé rẹ yípadà nípasẹ fífi Ìwé Mímọ́ se àkọ́sórí! Fún ètò kíkún fún fífi Ìwé Mímọ́ se àkọ́sórí, lọ sí www.MemLoK.com