Ọjọ́ Mẹ́rìn
Ìjìyà jẹ́ ọ̀kan lára ìpìlẹ̀ ìgbàgbọ́ Kristiẹni - 2 Timoti 3:12. Ìdáhùn rere rẹ sí-i máa dàgbà nípasẹ pípàdé Ọlọ́run àti ṣíṣàrò nínú Ọ̀rọ Rẹ̀. Àwọn ẹsẹ̀ tí ó tẹ̀lé-e, nígbà tí a bá há wọn sórí, lè fún ọ ní ìṣírí sí ìdáhùn Ọlọ́run sì ìjìyà.
Ọjọ́ Méje
Bóyá a nje ìrora ojú ogbé okàn tàbí tí ara, ìdaríji ní ìpìlê ìgbé ayé Kristẹni. Jésù Kristi nírírí onírúurú ohun tí kò tọ̀nà àti hùwàsí ti kódà títí dé ikú àìtó. Síbè ní wákàtí tó kéyìn, o daríji olè tó ṣe yèyé é lórí àgbélèbú àti bákan náà àwọn múdàájọ́ṣẹ e.